YORUBA LANGUAGE FIRST TERM EXAMINATION QUESTIONS FOR SSS 2

YORUBA LANGUAGE FIRST TERM EXAMINATION QUESTIONS FOR SSS 2

 

YORUBA LANGUAGE FIRST TERM EXAMINATION QUESTIONS FOR SSS 2

Advertisements

FIRST TERM EXAMINATION 2021

⇒Join us on Telegram for more Sure and Accurate football-winning tips every day...click here

SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

CLASS: S.S.S.2

Advertisements

1. Igba melo ni Musulumi maa n gbadura loojo? (a) igba mewaa  (b) igba marun-un  (d) igba meji

2. Awon wo ni o mu esin Musulumi wo ile adulawo? (a) awon ajinhinrere  (b) awon Larubawa  (d) awon atohunrinwa

3. Awon Musulumi maa n se odun itunu awe lehin awe ojo melo? (a) ogoji ojo (b) ogbon ojo  (d) ojo mewaa

4. Ilu wo ni a ti gbe esin Musulumi kale? (a) Ilu Larubawa  (b) Ilu Meka  (d) Ilu Asia

5. Ojo aiku je ojo isin Pataki fun awon _____ (a) elesin isembaye  (b) elesin Musulumi (d) elesin Onigbagbo

6. Odun ajoyo Pataki fun awon elesin Kristieni ni _____ (a) odun igbagbo  (b) odun ominira  (d) odun Keresimesi

7.Lara esin miran to n tiraka lati gbile ni ile adulawo ni _____ (a) esin Hindu  (b) esin oba  (d) esin omo iya

8. Ere idaraya ti o je ti awon omode ni _____ (a) ere ita gbangba  (b) ere ode oni (d) ere osupa

9. Apeere ere abele ni _____ (a) alo pipa  (b) ijakadi  (d) ere ipa

10. Oruko miran fun ijakadi ni _____ (a) ere owo  (b) eke  (d) ese kiku

11. Ere ita gbangba maa n ko omode ni iforiti (a) Beeni    (b) Beeko

12. Ewo ni kii se ere ode oni? (a) ere sisa  (b) ere ipa   (d) Ludo tita

13. Akojopo isori oro ti o fun wa ni itumo ni _____ (a) eyo oro  (b) gbolohun  (d) oro ise

14. Dide! Je apeere gbolohun _____ (a) gbolohun onibo  (b) gbolohun ase  (d) gbolohun abode

15. Mo fe ra oko ayokele kan bi oluwa ba pese owo re je apeere gbolohun _____ (a) gbolohun onibo  (b gbolohun aba  (d) gbolohun abode

16. Gbolohun ti o ni ju awe gbolohun kan lo ti o si le da duro funra re ni _____ (a) gbolohun ase  (b) gbolohun alakanpo  (d) gbolohun abode

17. Ara ise baale ni _____ (a) yiyanju aawo (b) gbigba iyawo wole  (d) ina dida

18. Kini oruko oye oba ilu Osogbo (a) Olubadan  (b) Ataoja  (d) Olomu

19. Ipinle wo ni Ijebujesa wa? (a) Ogun  (b) Osun  (d) Ekiti

20. Ba wo ni a se n polowo eran tutu? (a) E reran e sebe  (b) Yee, Obe!  (d) ooyo oko

21. Kini a n polowo bayi? Langbe jinna o  (a) ewa  (b) adalu   (d) agbado

22. Nibo ni a kii ti polowo oja ni ode oni ninu wonyi? (a) inu iwe iroyin  (b) ori ero alatagba kari aye  (d) oju ofurufu

23. Leta gbefe fi aye gba ikini ati aroye (a) Beeni   (b) Beeko

24. Adireesi meji ni o maa n wa ninu leta gbefe (a) Beeni    (b) Beeko

25. Leta ti ko fi aye gba ikini ati aroye ni _____ (a) leta si ore re ni ilu Eko  (b) leta aigbagbefe  (d) leta gbefe

26. “O maa to ojo meta” maa n jeyo ninu leta gege bi _____ (a) akole  (b) ikadii  (d) ikini

27. Leta gbefe kii ni _____ (a) oruko akoleta  (b) adiresi agbaleta  (d) deeti

28. Ojo ijosin Pataki fun awon Musulumi ni _____ (a) ojo aje  (b) ojoru  (d) ojo eti

29. Ara ise iyaale ni _____ (a) ija jija  (b) ina dida  (d) ejo riro

30. Sare! Je apeere gbolohun _____ (a) gbolohun ase  (b) gbolohun abuda  (d) gbolohun onibo

 

APA KEJI

1. Se akosile ranpe lori esin Musulumi

2. Daruko ere idaraya merin pelu apeere kookan

3. Daruko oye oba ilu wonyi

(a)        Oyo

(b)       Ikole – Ekiti

(d)       Abeokuta

(e)        Ilesa

(e)        Idanre

4. Ko bi a ti n polowo awon oja wonyi

(a)        agbado sise

(b)       Iyan

(d)       Eran tutu

(e)        Eweedu

(e)        Gaari

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *